Òwe Yorùbá D

Òwe Yorùbá D

⚀. Dá tọ́rọ́, dà tọ́rọ́, dá tọ́rọ́, àgbà tí kò dá tọ́rọ́ omi ọbẹ̀ ni yóò jẹ.
⚁. Dà bí mo ṣe dá tí mú kí ọlọ́kùnrùn sọ pé omitoro ejò ni òun fẹ je.
⚂. Dàda kò lè jà ṣùgbọ́n ó ní àbúrò tó gbójú.
⚃. Dán an wo ló bí ìyá Ọ̀kẹ́rẹ́.
⚄. Dẹ́ngẹ̀ tutù lẹ́hìn ó gbóná nínú.
⚅. Dìndìnrín kí I bá wọn lágbàlagbà kékeré ni ọmọ náà tí gọ̀ lọ.

Share:

Share on facebook
Share on twitter
Share on email
Share on whatsapp
Share on telegram

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *